1 Chronicles 21:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Inú Ọlọrun kò dùn sí ọ̀rọ̀ náà, nítorí náà ó jẹ àwọn ọmọ Israẹli níyà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nkan yi si buru loju Ọlọrun; o si kọlù Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àṣẹ yìí pẹ̀lú sì jẹ́ búburú lójú OLÚWA, bẹ́ẹ̀ ni ó sì díyàjẹ Ísírẹ́lì.