1 Chronicles 22:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Nisinsinyii, ìwọ ọmọ mi, OLUWA yóo wà pẹlu rẹ, kí o lè kọ́ ilé OLUWA Ọlọrun rẹ fún un gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ nípa rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ ọmọ mi, ki Oluwa ki o pẹlu rẹ; iwọ si ma pọ̀ si i, ki o si kọ́ ile Oluwa Ọlọrun rẹ, bi o ti sọ nipa tirẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nísinsìn yìí, ọmọ mi, kí OLÚWA wà pẹ̀lú rẹ, kí ìwọ kí ó sì ní àṣeyọrí kí o sì kọ́ ilé OLÚWA Ọlọ́run rẹ, àti gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ nípa rẹ.