1 Chronicles 22:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
àwọn alágbẹ̀dẹ wúrà, ati ti fadaka, ti idẹ, ati ti irin. Bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ náà nisinsinyii! Kí OLUWA wà pẹlu rẹ!”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Niti wura, fadakà ati idẹ, ati irin, kò ni ìwọn. Nitorina dide ki o si ma ṣiṣẹ, ki Oluwa ki o si pẹlu rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú wúrà, fàdákà àti idẹ àti irin onísọ̀nà tí kò ní ìwọ̀n. Nísinsin yìí bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́, kí OLÚWA wà pẹ̀lú rẹ.”