1 Chronicles 22:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dafidi pàṣẹ fún gbogbo àwọn àgbààgbà Israẹli pé kí wọ́n ran Solomoni, ọmọ òun lọ́wọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi paṣẹ pẹlu fun gbogbo awọn ijoye Israeli lati ran Solomoni ọmọ rẹ̀ lọwọ pe:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà Dáfídì pa á láṣẹ fún gbogbo àwọn àgbààgbà ní Ísírẹ́lì láti ran Sólónmónì ọmọ Rẹ̀ lọ́wọ́.