1 Chronicles 22:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dafidi pàṣẹ pé kí gbogbo àwọn àjèjì tí wọn ń gbé ilẹ̀ Israẹli péjọ, ó bẹ̀rẹ̀ sí kó wọn ṣiṣẹ́, ara wọn ni wọ́n gbẹ́ òkúta fún kíkọ́ tẹmpili.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si paṣẹ lati ko awọn alejo ti mbẹ ni ilẹ Israeli jọ; o si yan awọn agbẹkuta lati gbẹ okuta lati fi kọ́le Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni Dáfídì paláṣẹ láti kó àwọn àlejò tí ń gbé ní Ísírẹ́lì jọ, àti wí pé lára wọn ni ó ti yan àwọn agbé-òkúta láti gbé òkúta dáradára láti fi kọ́lé Ọlọ́run.