1 Chronicles 23:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Ṣimei jẹ́ mẹrin: Jahati, Sina, Jeuṣi, ati Beraya.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Ṣimei ni Jahati, Sina, ati Jeuṣi, ati Beriah. Awọn mẹrin wọnyi li ọmọ Ṣimei.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti ọmọ Ṣímélì: Jáhátì, Ṣísà, Jéúsì àti Béríà. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Ṣíméhì mẹ́rin ni gbogbo wọn.