1 Chronicles 23:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Kohati jẹ́ mẹrin: Amramu, Iṣari, Heburoni, ati Usieli,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Kohati; Amramu, Ishari, Hebroni ati Ussieli, mẹrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ kóhátì: Ámírámù, Ísárì, Hébúrónì àti Usíélì mẹ́rin ni gbogbo wọn.