1 Chronicles 23:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Geriṣomu ni: Ṣebueli, olórí ìdílé Geriṣomu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Gerṣomu, Sebueli li olori.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Gérísónì Ṣúbáélì sì ni alákọ́kọ́.