1 Chronicles 23:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Usieli bí ọmọ meji: Mika, tí ó jẹ́ olórí, ati Iṣaya.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Ussieli: Mika ekini, ati Jesiah ekeji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Húsíélì: Míkà ni àkọ́kọ́ àti Íṣíà ẹ̀ẹ̀kejì.