1 Chronicles 23:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Ladani jẹ́ mẹta: Jeieli tí ó jẹ́ olórí, Setamu ati Joẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Laadani: Jehieli ni olori, ati Setamu, ati Joeli, mẹta.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ládánì Jéhíélì ẹni àkọ́kọ́, Ṣétanì àti Jóẹ́lì ẹ̀kẹ́ta ní gbogbo wọn.