1 Chronicles 24:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn olórí ninu ìdílé àwọn ọmọ Lefi yòókù nìwọ̀nyí: Ṣubaeli láti inú ìdílé Amramu, Jedeaya láti inú ìdílé Ṣubaeli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iyokù awọn ọmọ Lefi ni wọnyi: Ninu awọn ọmọ Amramu; Ṣubaeli: ninu awọn ọmọ Ṣubaeli; Jehediah.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìyòókù àwọn ọmọ Léfì: láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ámúríamù: Ṣúbáelì; láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ṣúbáélì; Jédeíà.