1 Chronicles 24:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣelomiti láti inú ìdílé Iṣari, Jahati láti inú ìdílé Ṣelomiti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn Ishari; Ṣelomoti; ninu awọn ọmọ Ṣelomoti; Jahati.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Iṣárì: Ṣélómótì; láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ṣélomótì: Jáhátì.