1 Chronicles 24:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Iṣaya ni arakunrin Mika. Sakaraya láti inú ìdílé Iṣaya.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Arakunrin Mika ni Iṣṣiah; ninu awọn ọmọ Iṣṣiah; Sekariah.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn arákùnrin Míkà: Íṣíà; nínú àwọn ọmọ Íṣíà: Ṣekaríyà.