1 Chronicles 24:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Merari láti inú ìdílé Jaasaya ni Beno ati Ṣohamu, Sakuri ati Ibiri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Merari nipa Jaasiah; Beno ati Ṣohamu, ati Sakkuri, ati Ibri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Mérárì: Lati Jasíà: Bẹ́nò, Ṣóhámù, Ṣákúrì àti Íbírì.