1 Chronicles 24:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Muṣi ní ọmọkunrin mẹta: Mahili, Ederi, ati Jerimotu. Àkọsílẹ̀ àwọn ọmọ Lefi nìyí, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Muṣi pẹlu; Mali, ati Ederi, ati Jerimoti. Wọnyi li ọmọ awọn ọmọ Lefi nipa ile baba wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti àwọn ọmọ Muṣì: Málì, Édérì àti Jérímotì. Èyí ni àwọn ọmọ Léfì, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.