1 Chronicles 25:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Hemani ni: Bukaya, Matanaya, Usieli, Ṣebueli, ati Jerimotu, Hananaya, Hanani, Eliata, Gidaliti, ati Romamiti Eseri, Joṣibekaṣa, Maloti, Hotiri, ati Mahasioti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti Hemani: awọn ọmọ Hemani; Bukkiah, Mattaniah, Ussieli, Ṣebueli, ati Jerimotu, Hananiah, Hanani, Eliata, Giddalti, ati Romamtieseri, Joṣbekaṣa, Malloti, Hotiri, Mahasiotu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gẹ́gẹ́ bí ti Hémánì, nínú àwọn ọmọ Rẹ̀: Búkíà, Mátaníyà, Usíélì, Ṣúbáélì àti Jérímótì; Hánáníyà, Hánánì, Élíátà, Gídáítì àti Rámámútì Ésérì; Jósíbékáṣà, Málótì, Hótírì àti Máhásíótì.