1 Chronicles 25:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gègé ni wọ́n ṣẹ́ tí wọ́n fi mọ iṣẹ́ olukuluku; ati kékeré ati àgbà, ati olùkọ́ ati akẹ́kọ̀ọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si ṣẹ keké fun iṣẹ; gbogbo wọn bakanna bi ti ẹni-kekere bẹ̃ni ti ẹni-nla, ti olukọ bi ti ẹniti a nkọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kékeré àti àgbà bákan náà, olùkọ́ àti gẹ́gẹ́ bí ti ọmọléèwé, pin dànù fún isẹ́ wọn.