1 Chronicles 25:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gègé kinni tí wọ́n ṣẹ́ fún ìdílé Asafu mú Josẹfu; ekeji mú Gedalaya, òun ati àwọn arakunrin rẹ̀ ati àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin jẹ́ mejila.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iṣẹkeké ekini si jade wá fun Asafu si Josefu: ekeji si Gedaliah, ẹniti on pẹlu awọn arakunrin rẹ̀ ati awọn ọmọ rẹ̀, jẹ mejila:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Isẹ́kèké èkíni èyí tí ó jẹ́ ti Ásáfù, jáde sí Joṣéfù, àwọn ọmọ Rẹ̀ àti ìdílé Rẹ̀ jẹ́, — méjìlá ekejì sì ni Gédálíà, òun àti àwọn ìdílé Rẹ̀ àti àwọn ọmọ Rẹ̀, — méjìlá