1 Chronicles 26:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí a ti ṣe pín iṣẹ́ fún àwọn aṣọ́nà nìwọ̀nyí: Meṣelemaya, ọmọ Kore, ní ìdílé Asafu, ninu ìran Kora.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NITI ipin awọn adena: niti awọn ọmọ Kosa ni Meṣelemiah ọmọ Kore, ninu awọn ọmọ Asafu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìpín tí àwọn olùtọ́jú ẹnu ọ̀nà: Láti ọ̀dọ̀ Kórà: Méṣélémíò ọmọ Kórè, ọ̀kan lára àwọn ọmọ Áṣáfì.