1 Chronicles 26:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Meṣelemaya bí ọmọ meje, orúkọ wọn nìyí gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ orí wọn, Sakaraya ni àkọ́bí, lẹ́yìn náà Jediaeli, Sebadaya, ati Jatinieli;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Meṣelemiah ni Sekariah akọbi, Jediaeli ekeji, Sebadiah ẹkẹta, Jatnieli ẹkẹrin,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Méṣélémíà ní àwọn ọmọkùnrin: Ṣékáríáyà àkọ́bí, Jédíáélì ẹlẹ́ẹ̀kejì, Ṣébádíáyà ẹlẹ́ẹ̀kẹta, Játiníẹ́lì ẹlẹ́ẹ̀kẹ́rin,