1 Chronicles 26:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A pín iṣẹ́ fún àwọn ọmọ Amramu, ati àwọn ọmọ Iṣari, ati àwọn ọmọ Heburoni ati àwọn ọmọ Usieli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu ọmọ Amramu, ati ọmọ Ishari, ara Hebroni, ati ọmọ Ussieli:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti ọ̀dọ̀ àwọn ará Ámírámù, àwọn ará Íṣíhárì, àwọn ará Hébírónì àti àwọn ará Úṣíélì.