1 Chronicles 26:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣebueli, ọmọ Geriṣomu, láti inú ìran Mose, ni olórí àwọn tí ń bojútó ibi ìṣúra.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Ṣebueli ọmọ Gerṣomu, ọmọ Mose, ni onitọju iṣura.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣúbáélì, ìran ọmọ Gérísómì ọmọ Mósè jẹ́ oníṣẹ́ tí ó bojútó ilé ìṣúra