1 Chronicles 26:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọmọ mẹjọ ni Obedi Edomu bí nítorí pé Ọlọrun bukun un. Orúkọ àwọn ọmọ náà nìyí, bẹ̀rẹ̀ láti orí àkọ́bí: Ṣemaaya, Jehosabadi, ati Joa; Sakari, ati Netaneli;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Obed-Edomu si ni Ṣemaiah akọbi, Jehosabadi ekeji, Joa ẹkẹta, ati Sakari ẹkẹrin, ati Netaneeli ẹkarun,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Obedi-Édómù ni àwọn ọmọkùnrin pẹ̀lú: Ṣémáíà àkọ́bí, Jéhóṣábádì ẹlẹ́ẹ̀kejì, Jóà ẹlẹ́ẹ̀kẹta, Ṣákárì ẹlẹ́ẹ̀kẹrin, Nétanélì ẹlẹ́ẹ̀kaàrún,