1 Chronicles 26:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Meṣelemaya ati àwọn arakunrin rẹ̀ tí wọ́n lágbára jẹ́ mejidinlogun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Meṣelemiah si ni awọn ọmọ ati arakunrin, alagbara enia, mejidilogun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Móésélémíà ní àwọn ọmọ àti àwọn ìbátan, tí ó jẹ́ alágbára méjìdínlógún (18) ni gbogbo wọn.