1 Chronicles 27:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n jẹ́ olórí ninu àwọn ẹ̀yà Israẹli nìwọ̀nyí, láti inú ẹ̀yà Reubẹni: Elieseri, ọmọ Sikiri ni olórí patapata. Láti inú ẹ̀yà Simeoni: Ṣefataya, ọmọ Maaka.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati lori awọn ẹ̀ya Israeli: ijoye lori awọn ọmọ Reubeni ni Elieseri ọmọ Sikri: lori awọn ọmọ Simeoni, Ṣefatiah ọmọ Maaka:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìjòyè lórí àwọn ẹ̀yà tí Ísírẹ́lì: lórí àwọn ará Réúbẹ́nì: Éliésérì ọmọ Ṣíkírì; lórí àwọn ará Ṣíméónì: Ṣéfátíyà ọmọ Mákà;