1 Chronicles 27:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
láti inú ẹ̀yà Juda: Elihu, ọ̀kan ninu àwọn arakunrin Dafidi; láti inú ẹ̀yà Isakari: Omiri, ọmọ Mikaeli;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lori Juda, Elihu, ọkan ninu awọn arakunrin Dafidi: lori Issakari, Omri ọmọ Mikaeli:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
lórí Júdà: Élíhù arákùnrin Dáfídì; lóri Ísákárì: Ómírì ọmọ Míkáélì;