1 Chronicles 27:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti inú ẹ̀yà Efuraimu: Hoṣea, ọmọ Asasaya; láti inú ìdajì ẹ̀yà Manase: Joẹli, ọmọ Pedaya;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lori awọn ọmọ Efraimu, Hoṣea ọmọ Asasiah: lori àbọ ẹ̀ya Manasse, Joeli ọmọ Pedaiah.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
lórí àwọn ará Éfíráímù: Hòṣéà ọmọ Áṣásíà; lorí ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè: Jóélì ọmọ Pedáyà;