1 Chronicles 27:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
láti inú ẹ̀yà Dani: Asareli, ọmọ Jerohamu. Àwọn ni olórí àwọn ẹ̀yà Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lori Dani, Asareeli ọmọ Jerohamu Awọn wọnyi li olori awọn ẹ̀ya Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
lórí Dánì: Áṣárélì ọmọ Jéróhámù. Wọ̀nyí ni àwọn ìjòyè lórí ẹ̀yà Ísírẹ́lì.