1 Chronicles 27:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Esiri, ọmọ Kelubu, ni alabojuto fún gbogbo iṣẹ́ oko dídá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati lori awọn ti nro oko, lati ma ro ilẹ ni Esri ọmọ Kelubi wà:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ésírì ọmọ kélúbì wà ní ìdí àwọn òṣìṣẹ́ lórí pápá, tí wọ́n ń ko ilẹ̀ náà.