1 Chronicles 27:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo wọn jẹ́ alabojuto àwọn ohun ìní Dafidi ọba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati lori agbo agutan ni Jasisi ara Hageri wà. Gbogbo awọn wọnyi ni ijoye ohun ini ti iṣe ti Dafidi ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jáṣíṣì ará Hágírì wà ní ìdi àwọn agbo-ẹran. Gbogbo wọ̀nyí ni àwọn oníṣẹ́ tí wọ́n wà ní ìdí ẹrù ọba Dáfídì.