1 Chronicles 28:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kíyèsára, nítorí pé OLUWA ti yàn ọ́ láti kọ́ ilé kan tí yóo jẹ́ ibi mímọ́, ṣe gírí, kí o sì kọ́ ọ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wò o nisisiyi: nitori Oluwa ti yàn ọ lati kọ́ ile kan fun ibi mimọ́, mura le, ki iwọ si ṣe e.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbèrò báyìí nítorí tí OLÚWA ti yàn ọ́ láti kọ́ ilé OLÚWA gẹ́gẹ́ bí ilé tí a yà sí mímọ́ fún OLÚWA. Jẹ́ alágbára kí ó sì ṣe iṣẹ́ náà.”