1 Chronicles 28:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ati àwòrán gbogbo ohun tí ó ní lọ́kàn láti ṣe sinu àgbàlá ilé OLUWA, ati ti àwọn yàrá káàkiri, àwọn ilé ìṣúra tí yóo wà ninu ilé Ọlọrun, ati ti àwọn ilé ìṣúra tí wọ́n o máa kó ohun tí a yà sọ́tọ̀ fún OLUWA pamọ́ sí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati apẹrẹ gbogbo eyi ti o ni ni inu rẹ̀ pẹlu rẹ̀ niti agbala ile Oluwa, ati ti gbogbo iyara yikakiri, niti ibi iṣura ile Ọlọrun, ati niti ibi iṣura ohun ti a yà-si-mimọ́:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó fún un ní àwọn ètò gbogbo èyí tí ẹ̀mí ti fi sí ọkàn Rẹ̀ fún ti ààfin ilé OLÚWA àti gbogbo yàrá tí ó yíká fún ìṣúra ilé Ọlọ́run àti fún ìṣúra fún ohun yíyà sọ́tọ̀.