1 Chronicles 28:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ti ìwọ̀n àwọn ọ̀pá fìtílà wúrà ati àwọn fìtílà wọn, ti ìwọ̀n fadaka fún ọ̀pá fìtílà kan ati àwọn fìtílà wọn, gẹ́gẹ́ bí ìlò olukuluku wọn ninu ìsìn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ìwọn ọpa fitila wura, ati fitila wura wọn, nipa ìwọn fun olukuluku ọpa fitila ati ti fitila rẹ̀: ati niti ọpa fitila fadakà nipa ìwọn, ti olukuluku ọpa fitila ati ti fitila rẹ̀, gẹgẹ bi ìlo olukuluku ọpa fitila.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ̀n wúrà fún ìdúró fìtílà àti fìtílà wọn, fún ìwọ̀n fún ọ̀kọ̀ọ̀kan ìdúró fìtílà àti fìtílà wọn; àti ìwọ̀n fàdákà ìdúró fìtilà fàdákà àti àwọn fìtílà Rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ìlò ti gbogbo ìduró fìtílà.