1 Chronicles 28:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo nǹkan wọnyi ni ó kọ sílẹ̀ fínnífínní gẹ́gẹ́ bí ìlànà láti ọ̀dọ̀ OLUWA nípa iṣẹ́ inú tẹmpili; ó ní gbogbo rẹ̀ ni wọ́n sì gbọdọ̀ ṣe gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo eyi wà ninu iwe lati ọwọ Oluwa ẹniti o kọ́ mi niti gbogbo iṣẹ apẹrẹ wọnyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Gbogbo èyí,” ni Dáfídì wí pé, “Èmi ní kíkọ sílẹ̀ láti ọwọ́ OLÚWA sórí mi, ó sì fún mí ní ìmọ̀ nínú gbogbo iṣẹ́ ètò yìí.”