1 Chronicles 29:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo àwọn ìjòyè, àwọn alágbára, ati gbogbo àwọn ọmọ Dafidi ọba ni wọ́n jẹ́jẹ̀ẹ́ láti máa gbọ́ ti Solomoni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati gbogbo awọn ijoye, ati awọn alagbara, ati pẹlu gbogbo awọn ọmọ Dafidi ọba tẹri wọn ba fun Solomoni ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn ìjòyè àti àwọn ọkùnrin alágbára, pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ ọba Dáfídì tẹrí ara wọn ba fún ọba Sólómónì.