1 Chronicles 29:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA gbé Solomoni ga lójú gbogbo àwọn ọmọ Israẹli, ó sì fún un ní ọlá ju gbogbo àwọn ọba tí wọ́n ti jẹ ṣáájú rẹ̀ ní Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa si gbé Solomoni ga gidigidi li oju gbogbo Israeli, o si fi ọlá nla ọba fun u bi iru eyi ti kò wà fun ọba kan ṣaju rẹ̀ lori Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA gbé Solómónì ga púpọ̀ ní ojú gbogbo Ísírẹ́lì, ó sì kẹ́ ẹ ní ìkẹ́ ọlá ńlá, ní irú èyí tí a kò kẹ́ ọba kankan ṣáájú Rẹ̀ tí ó jẹ lórí Ísírẹ́lì.