1 Chronicles 29:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, yàtọ̀ fún gbogbo àwọn nǹkan tí mo ti pèsè fún Tẹmpili Ọlọrun mi, mo ní ilé ìṣúra ti èmi alára, tí ó kún fún wúrà ati fadaka, ṣugbọn nítorí ìfẹ́ mi sí ilé Ọlọrun mi, mo fi wọ́n sílẹ̀ fún iṣẹ́ ilé náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlupẹlu, nitori ni didùn inu mi si ile Ọlọrun mi, mo fi ohun ini mi, eyinì ni wura ati fadakà, fun ile Ọlọrun mi, jù gbogbo eyi ti mo ti pèse silẹ fun ile mimọ́ na,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yàtọ̀ fún èyí, nínú ìfọkànsìn mi sí ilé Ọlọ́run mi, èmí fi ìṣúra mi tìkalára mí ti wúrà àti fàdákà fún ilé Ọlọ́run mi, jù gbogbo Rẹ̀ lọ, èmi ti pèṣè fún ilé mímọ́ ti OLÚWA yìí: