1 Chronicles 29:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo ti pèsè ẹgbẹẹdogun (3,000) ìwọ̀n talẹnti wúrà dáradára láti ilẹ̀ Ofiri, ati ẹẹdẹgbaarin (7,000) ìwọ̀n talẹnti fadaka tí a ti yọ́, láti fi bo gbogbo ògiri tẹmpili náà,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹgbẹ̃dogun talenti wura, ti wura Ofiri, ati ẹ̃dẹgbarin talenti fadakà didara, lati fi bo ogiri ile na:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) talẹ́ntì wúrà (wúrà ti ofírì) àti ẹgbẹ̀rin méje tálẹ́ntì fàdákà tí a yọ̀rọ̀ kúrò, fún bíbo àwọn ògiri ilé náà.