1 Chronicles 3:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Dafidi tí a bí fún un ní Heburoni nìwọ̀nyí, bí wọ́n ṣe tẹ̀lé ara wọn: Aminoni tí Ahinoamu ará Jesireeli bí fún un ni àkọ́bí rẹ̀, lẹ́yìn rẹ̀ ni Daniẹli, ọmọ Abigaili ará Kamẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
WỌNYI li awọn ọmọ Dafidi, ti a bi fun u ni Hebroni; akọbi Amnoni, lati ọdọ Ahinoamu ara Jesreeli; ekeji Danieli, lati ọdọ Abigaili ara Karmeli;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ Dáfídì tí a bí fún un ní Hébírónì: Àkọ́bí sì ni Ámínónì ọmọ Áhínóámù ti Jésírẹ́lì; èkejì sì ni Dáníẹ́lì ọmọ Ábígáílì ará Kárímélì;