1 Chronicles 3:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Orúkọ àwọn ọmọ Josaya mẹrẹẹrin, bí wọ́n ṣe tẹ̀lé ara wọn ni: Johanani, Jehoiakimu, Sedekaya ati Ṣalumu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Josiah; akọbi Johanani, ekeji Jehoiakimu, ẹkẹta Sedekiah, ẹkẹrin Ṣallumu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Jósíà: Àkọ́bí ọmọ Rẹ̀ ni Jóhánánì, èkejì ọmọ Rẹ̀ ni Jéhóíákímù, ẹ̀kẹta ọmọ Rẹ̀ ni Ṣédékíà, ẹ̀kẹ́rin ọmọ Rẹ̀ ni Ṣálúmù.