1 Chronicles 3:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Pedaaya bí ọmọ meji: Serubabeli, ati Ṣimei. Serubabeli bí ọmọ meji: Meṣulamu ati Hananaya, ati ọmọbinrin kan tí ń jẹ́ Ṣelomiti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Pedaiah; Serubbabeli; ati Ṣimei; ati awọn ọmọ Serubbabeli; Meṣullamu, ati Hananiah, ati Ṣelomiti arabinrin wọn:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Pédáíyà: Ṣérúbábélì àti Ṣíméhì. Àwọn ọmọ Ṣérúbábélì: Mésúlámù àti Hánáníyà, Ṣélómítì ni arábìnrin wọn.