1 Chronicles 3:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣekanaya ní ọmọ kan, tí ń jẹ́ Ṣemaaya. Ṣemaaya bí ọmọ marun-un: Hatuṣi, Igali, Baraya, Nearaya ati Ṣafati.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Ṣekaniah; Ṣemaiah; ati awọn ọmọ Ṣemaiah; Hettuṣi, ati Igeali, ati Bariah, ati Neariah, ati Ṣafati, mẹfa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ṣékáníà: Ṣémáíà àti àwọn ọmọ Rẹ̀: Hátúsì, Ígéálì, Báríà, Néáríà àti Ṣáfátì, mẹ́fà ni gbogbo wọn.