1 Chronicles 3:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Elioenai bí ọmọ meje: Hodafaya, Eliaṣibu, Pelaaya, Akubu, Johanani, Delaaya ati Anani.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Elioenai ni, Hodaiah, ati Eliaṣibu, ati Pelaiah, ti Akkubu, ati Johanani, ati Dalaiah, ati Anani, meje.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Élíóéníà: Hódáíà, Élíásíbù, Pétéláéà, Ákúbù, Jóhánánì, Déláyà àti Ánánì, méje sì ni gbogbo wọn.