1 Chronicles 4:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kenasi bí ọmọ meji: Otinieli ati Seraaya. Otinieli náà bí Hatati ati Meonotai.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Kenasi; Otnieli, ati Seraiah: ati awọn ọmọ Otnieli; Hatati.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Kénásì: Otíníẹ́lì àti Ṣéráíà. Àwọn ọmọ Ótiníẹ́lì: Hátatì àti Méónótaì.