1 Chronicles 4:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Meonotai ni baba Ofira. Seraaya sì ni baba Joabu, baba àwọn ará Geharaṣimu, ìlú àwọn oníṣọ̀nà. Àwọn ni wọ́n tẹ gbogbo pẹ̀tẹ́lẹ̀ àwọn oníṣẹ́ ọwọ́ dó.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Meonotai si bi Ofra: Seraiah si bi Joabu, baba Geharasimu; nitori oniṣọnà ni nwọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Méónótaì sì ni baba Ófírà. Ṣéráíà sì jẹ́ baba Jóábù, baba Géhárásínù. A pè báyìí nítorí àwọn ènìyàn àwọn onísọ́nà niwọ́n.