1 Chronicles 4:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Hodia fẹ́ arabinrin Nahamu, àwọn ọmọ wọn ni wọ́n ṣẹ ẹ̀yà Garimi, tí wọn ń gbé ìlú Keila sílẹ̀, ati àwọn ìran Maakati tí wọn ń gbé ìlú Eṣitemoa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ aya Hodiah, arabinrin Nahamu, baba Keila, ara Garmi, ati Eṣtemoa ara Maaka:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ aya Hódíyà arábìnrin Náhámù: Baba Kéílà ará Gárímì, àti Ésítémóà àwọn ará Mákà.