1 Chronicles 4:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣela, ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Juda, ni baba Eri, baba Leka. Laada ni baba Mareṣa, ati ìdílé àwọn tí wọ́n ń hun aṣọ fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ funfun ní Beti Aṣibea
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Ṣela, ọmọ Juda ni, Eri baba Leka, ati Laada baba Mareṣa ati idile ile awọn ti nwọn nwun aṣọ ọ̀gbọ daradara, ti ile Aṣbea,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ṣélà ọmọ Júdà: Érì baba Lékà, Ládà baba Máréṣà àti àwọn ìdílé ilé àwọn tí ń wun aṣọ oníṣẹ́ ní Bẹti-Áṣíbéà.