1 Chronicles 4:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ati Jokimu, ati àwọn ará ìlú Koseba, Joaṣi ati Sarafu, tí wọ́n fi ìgbà kan jẹ́ alákòóso ní Moabu, tí wọ́n sì pada sí Bẹtilẹhẹmu. (Àkọsílẹ̀ yìí jẹ́ ti àtijọ́.)
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Jokimu, ati awọn ọkunrin Koseba, ati Joaṣi, ati Sarafu, ti o ni ijọba ni Moabu, ati Jaṣubilehemu. Iwe iranti atijọ ni wọnyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tókímù, ọkùnrin kósébà, àti Jóáṣì àti sáráfù, olórí ní Móábù àti Jáṣúbì Léhémù. (Àkọsílẹ̀ yìí sì wà láti ìgbà àtijọ́).