1 Chronicles 4:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Beti Makabotu, Hasasusimu, Betibiri, ati Ṣaaraimu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ni Bet-markaboti, ati ni Hasar-susimu, ati ni Bet-birei, ati Ṣaaraimu. Awọn wọnyi ni ilu wọn, titi di ijọba Dafidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹti máríkóbótì Hórímà; Hásárì Ṣúsímù, Bẹti Bírì àti Ṣáráímì. Àwọn wọ̀nyí ni ìlú wọn títí di ìgbà ọba Dáfídì,