1 Chronicles 4:33 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
àwọn ìlú marun-un pẹlu àwọn ìgbèríko tí ó yí wọn ká títí dé ìlú Baali. Àwọn agbègbè náà ni wọ́n ń gbé, wọ́n sì ní àkọsílẹ̀ ìdílé wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati gbogbo ileto wọn, ti o wà yi ilu na ka, de Baali. Wọnyi ni ibugbe wọn, ati itan idile wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti gbogbo ìletò tí ó wà ní agbégbé àti gẹ́gẹ́ bí ó ti dé Bálì Àwọn wọ̀nyí ni ibùgbé wọn, wọ́n sì pa ìwé ìtàn ìdílé mọ́.